Nàkádà Kẹta

The Amọ̀ Narmeri, thought to mark the unification of Upper and Lower Egypt; note the images of Hathor at the top and bottom, as well as the lionesses, symbols of Sekhmet, forming the central intertwined image

Nàkádà Kẹta ni igba to pari igba Nawada to siwaju igba Egypti ayeijoun, igba na bere lati 3200 de 3000 SK.[1] Igba yi gan ni igbese to da orileijoba sile, to ti bere lati igba Nakada keji, bere daada, pelu awon oba olori. Nakada Keta tun unje titokasi bi Iran-oba 0 tabi Igba Iran-oba akobere[2] lati fihan pe oba olori wa nibe otilejepe oba yi le mo je lati iran-oba kankan.


  • itokasi

Itokasi

  1. Shaw, Ian, ed (2000). The Oxford History of Ancient Egypt. Oxford University Press. p. 479. ISBN 0-19-815034-2. 
  2. Shaw, Ian, ed (2000). The Oxford History of Ancient Egypt. Oxford University Press. p. 479. ISBN 0-19-815034-2. 
Other Languages
asturianu: Naqada III
català: Naqada III
English: Naqada III
español: Naqada III
euskara: Naqada III
magyar: Nagada III
Bahasa Indonesia: Naqada III
italiano: Naqada III
ქართული: ნაქადა III
Latina: Naqada III
polski: Nagada III
português: Cultura Semaineana
русский: Некада III
සිංහල: නැකාඩා III
Tagalog: Naqada III
українська: Накада III