Bernardo Houssay

Bernardo Houssay
Bernardo Houssay
Ìbí(1887-04-10)Oṣù Kẹrin 10, 1887
Buenos Aires, Argentina
Aláìsí

Oṣù Kẹ̀sán 21, 1971 (ọmọ ọdún 84)


Oṣù Kẹ̀sán 21, 1971(1971-09-21) (ọmọ ọdún 84)
Buenos Aires, Argentina
Ọmọ orílẹ̀-èdèArgentine
PápáPhysiology, endocrinology
Ó gbajúmọ̀ fúnGlucose
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize for Physiology or Medicine (1947)

Bernardo Alberto Houssay (April 10, 1887 – September 21, 1971) je Argentine onimo oro-edainuara to gba idaji Ebun Nobel fun Iwosan ni 1947, fun iwari to se nipa ipa ti pituitary hormones unko ninu akoso iye suga eje (glukosi) ninu awon eranko. Ohun ni ara Argentina ati Latin Amerika akoko elebun Nobel laureate ninu awon sayensi. (O pin ebun na pelu Carl Ferdinand Cori ati Gerty Cori, ti won gba fun iwari ti won se nipa ipa ti glukose unko ninu isemetabolisti karboniolomi.)[1] je onimo sayensi .


  • itokasi

Itokasi

Other Languages
български: Бернардо Усай
čeština: Bernardo Houssay
français: Bernardo Houssay
Bahasa Indonesia: Bernardo Alberto Houssay
lietuvių: Bernardo Houssay
Nederlands: Bernardo Houssay
português: Bernardo Houssay
Runa Simi: Bernardo Houssay
Simple English: Bernardo Houssay
Kiswahili: Bernardo Houssay
oʻzbekcha/ўзбекча: Bernardo Houssay
Tiếng Việt: Bernardo Houssay