Benito Mussolini

Benito Mussolini
Mussolini biografia.jpg
40th Prime Minister of Italy
In office
31 October 1922 – 25 July 1943
MonarchVictor Emmanuel III
AsíwájúLuigi Facta
Arọ́pòPietro Badoglio (Provisional Military Government)
First Marshal of the Empire
Lórí àga
30 March 1938 – 25 July 1943
Arọ́pòPietro Badoglio
Duce of the Italian Social Republic
Lórí àga
23 September 1943 – 26 April 1945
Personal details
Ọjọ́ìbí(1883-07-29)29 Oṣù Keje 1883
Predappio, Forlì, Italy
Aláìsí28 April 1945(1945-04-28) (ọmọ ọdún 61)
Giulino di Mezzegra, Italy
NationalityItalian
Ẹgbẹ́ olóṣèluRepublican Fascist Party
(1943-1945)
National Fascist Party
(1921-1943)
Italian Socialist Party
(1901-1914)
Spouse(s)Rachele Mussolini
ProfessionPolitician, Journalist

Benito Mussolini je oloselu omo orile-ede Italia. Wọ́n bí Benito ní 1883. Ó kú ní 1945. Òun ni ó dá Fasisti sílẹ̀ ní Italy. Òun ni ó darí Italy ní 1922 sí 1943. Agbára ni ó fi ń darí ilẹ̀ náà (a dictator). It Duce tí ó dúró fún olórí (the leader) ni àwọn èyìn rẹ̀ máa ń pè é. Mussolini àti ìgbìmọ̀ Fascist Party ni wọn jọ ń darí Italy. Wọn kò gba alátakò kankan láyè.

Gẹ́gẹ́ bí ajàfún-mèkúnnù (socialist) ni Mussohni ṣe wọ òṣèlú. Ó jẹ́ olóòtu ìwé-ìróyìn kan tí ó ń jẹ́ ní Avanti ṣùgbọ́n ní 1914, ó dá ìwé-ìroyìn tirẹ̀ sílẹ̀. Ó pè é ní IL Popolo d’Italia. Ní ọdún 1921 ni ó dá ẹgbẹ́ òṣèlú Fascist sile. Èrò tí ó ní nípa dídá ẹgbẹ́ òsẹ̀lú yìí sílẹ̀ ni láti lè tún Italy kọ́ kí ó sì sọ ọ́ di ìlú tí ó lágbára. Lẹ́yìn ìgbà tí àwọn Fascist rìn lọ sí Róòmù ní 1922 (‘Fascist March on Rome’), Ọba Victor Emmanuel III pe Mussoline láti wá gbé ìjọba tirẹ̀ kalẹ̀. Kò pẹ́ tí àwọn Fascist bẹ̀rẹ̀ síí darí ilẹ̀ Italy.

Àwọn ọmọ ogun Mussoline kọlu Ethopia ní 1905 wọ́n sì ṣẹ́gun ibẹ̀ lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjà tí ó gbóná. Kò pé tí Mussolini ní kí àwọn ọmọ ogun òun lọ ran General Franco lọ́wọ́ nínú ogun abẹ́lé ilẹ̀ Spain. Ní 1940, Italy bẹ̀rẹ̀ síí kópa nínú ogun àgbáyé kejì. Italy dúró gbá gbá gba ti Germany ṣùgbọ́n wọ́n ṣẹ́gun Italy. Won di ebi ifidírẹmi Italy yìí ru Mussolini. Wọ́n gba ìjọba lọ́wọ́ rẹ̀ wọ́n sì sọ ọ́ sí ẹ̀wọ̀n. Àwọn German gba á sílẹ̀ ó wa di olórí ìjọbá tí kò fẹsẹ̀ múlẹ̀ kan. Ní ọdún 1945, àwọn tí ó ń jà rí i mú, wọ́n sì pa á.


Other Languages
Afrikaans: Benito Mussolini
Alemannisch: Benito Mussolini
አማርኛ: ሙሶሊኒ
aragonés: Benito Mussolini
asturianu: Benito Mussolini
azərbaycanca: Benito Mussolini
žemaitėška: Benits Mosuolėnės
беларуская: Беніта Мусаліні
беларуская (тарашкевіца)‎: Бэніта Мусаліні
български: Бенито Мусолини
brezhoneg: Benito Mussolini
Mìng-dĕ̤ng-ngṳ̄: Benito Mussolini
čeština: Benito Mussolini
emiliàn e rumagnòl: Benito Mussolini
Esperanto: Benito Mussolini
estremeñu: Benito Mussolini
français: Benito Mussolini
Nordfriisk: Benito Mussolini
Gàidhlig: Benito Mussolini
Bahasa Indonesia: Benito Mussolini
íslenska: Benito Mussolini
Lëtzebuergesch: Benito Mussolini
Lingua Franca Nova: Benito Mussolini
لۊری شومالی: بنیتو موسولینی
lietuvių: Benito Mussolini
latviešu: Benito Musolīni
македонски: Бенито Мусолини
മലയാളം: മുസ്സോളിനി
Bahasa Melayu: Benito Mussolini
Mirandés: Benito Mussolini
مازِرونی: بنیتو موسولینی
नेपाल भाषा: बेनिटो मुसोलिनी
Nederlands: Benito Mussolini
norsk nynorsk: Benito Mussolini
Papiamentu: Benito Mussolini
Piemontèis: Benito Mussolini
پنجابی: میسولینی
português: Benito Mussolini
Runa Simi: Benito Mussolini
संस्कृतम्: बेनितो मुसोलिनी
sicilianu: Benitu Mussolini
srpskohrvatski / српскохрватски: Benito Mussolini
Simple English: Benito Mussolini
slovenčina: Benito Mussolini
slovenščina: Benito Mussolini
Soomaaliga: Benito Mussolini
српски / srpski: Бенито Мусолини
Basa Sunda: Benito Mussolini
Kiswahili: Benito Mussolini
ślůnski: Benito Mussolini
తెలుగు: ముస్సోలినీ
татарча/tatarça: Benito Mussolini
українська: Беніто Муссоліні
oʻzbekcha/ўзбекча: Benito Mussolini
Tiếng Việt: Benito Mussolini
მარგალური: ბენიტო მუსოლინი
文言: 墨索里尼
Bân-lâm-gú: Benito Mussolini
粵語: 墨索里尼